Friday, March 20, 2015

IWO TO FE WA LA O MA SIN

IWO TO FE WA LA O MA SIN TITI
1. I wo to fe wa la o ma sin titi
Oluwa Olore wa
Iwo to n so wa n’nu idanwo aye
Mimo, logo ola re

Baba, iwo l’a o ma sin
Baba, iwo l’a o ma bo
Iwo to fe wa l’a o ma sin titi
Mimo l’ogo ola re.


2. Iwo to nsure s’ohun t’a gbin s’aye
T’aye fi nrohun je o
Awon to mura lati ma s’oto
Won tun nyo n’nu ise re.

3. Iwo to nf’agan lomo to npe ranse
Ninu ola re to ga
Eni t’o ti s’alaileso si dupe
Fun ‘se ogo ola re

4. Eni t’ebi npa le ri ayo ninu
Agbara nla re to ga
Awon to ti nwoju re fun anu
Won tun nyo n’nu ise re.

5. F’alafia re fun ijo re l’aye
K’ore-ofe re ma ga;
k’awon eni tire ko ma yo titi
ninu ogo ise re. Amin.

26 comments:

  1. Thank you Jesus for this song. Mimo logo ola re Eledumare Oga Ogo

    ReplyDelete
  2. iwo to fe wa lAO MA yin titi. amin.

    ReplyDelete
  3. Lord am greatful for dis wonderful song.

    ReplyDelete
  4. Baba Iwo la o ma sin, titi lailai!

    ReplyDelete
  5. Glory to God in the highest for His awesomeness.

    ReplyDelete
  6. Great is thy faithfulness oh God!

    ReplyDelete
  7. He is d only one.to be.praised
    🙏

    ReplyDelete
  8. Thanks for sharing this song. Grace to you sir.

    ReplyDelete
  9. Igba akoko re e ti mo se alabapade ikanni yi. Mo dupe lowo Olorun fun oreofe ti o fun yin. Oluwa yi o tun bo maa so agbara d'otun. Olugbala a mu gbogbo wa dele o loruko Jesu Kristi.

    I'm blessed with the hymns. Stay blessed too.

    ReplyDelete