Yoruba Hymns

Monday, January 18, 2016

OLUWA mbo; ayé o mi,

›
OLUWA mbo; ayé o mi, Oke y'o sidi n'ipo won, At' irawo oju orun, Y'o mu imole won kuro. Oluwa mbo; bakan naa ko, ...

L'oju ale, 'gbat 'orun wo,

›
L'oju ale, 'gbat 'orun wo, Won gbe abirun w'odo Re; Onirum ni aisan won, Sugbon won fayo lo 'Ie won Jesu a de...

Baba, a tun pade l'oko Jesu

›
Baba, a tun pade l'oko Jesu A si wa teriba lab'ese Re A tun fe gb‘ohun wa soke si O Lati Wa anu, lati korin 'yin. Ayin...

Nigba kan ni Betlehemu

›
Nigba kan ni Betlehemu Ile kekere kan wa Nib'i'ya kan te mo're si Lori ibuje eran Maria n'iya omo na Jesu Kristi ...
1 comment:

B'olorun Oba orun

›
B'olorun Oba orun Ti ma nsoro n'igba ni; Otun ba wa soro be loni Arakunrin, oto ni Ohun t'Oba wi fun o; Ohun kan l...
Sunday, January 17, 2016

OLUWA mi, mo n jade lọ - Forth in Thy Name, O Lord, I go

›
OLUWA mi, mo n jade lọ, Lati se isẹ ojọ mi, Iwọ nikan l'emi o mọ, L'ọrọ, l'ero, ati n'ise. Isẹ t'o yan mi l...
4 comments:

WA s'adura oorọ,

›
WA s'adura oorọ, Kunlẹ k'a gbadura; Adura ni ọpa Kristiani, Lati b'Ọlọrun rin. Lọsan, wolẹ labẹ, Apat' ayeraye;...
1 comment:
›
Home
View web version

About Me

Sam O Salau www.SamOSalau.com.ng
View my complete profile
Powered by Blogger.