L’ oju ale gbat’ orun wo
1. L’ oju ale
gbat’ orun wo
Nwon gbe
abirun w’ odo Re
Oniruru ni
aisan won
Sugbon nwon
f’ ayo lo ‘le won
2. Jesu a de l’
oj’ ale yi
A sunmo t’
awa t’ arun wa
Bi a ko tile
le ri O
Sugbon a mo
p’ O sunmo wa
3. Olugbala wo
osi wa
Omi ko san
mi banuje
Omi ko ni
ife si O
Ife elomi si
tutu
4. Omi mo pea
san laiye
Benin won ko
f’ aiye sile
Omi l’ ore
ti ko se ‘re
Beni nwon ko
fi O s’ ore
5. Ko s’ okan
ninu wa t’ o pe
Gbogbo wa si
ni elese
Awon t’ o si
nsin O toto
Mo ara won
ni alaipe
6. Sugbon Jesu
Olugbala
Eni bi awa
n’ Iwo ‘se
‘Wo ti ri
‘danwo bi awa
‘Wo si ti mo
ailera wa
Thank you for the hymn. GOD Bless
ReplyDeleteThank you for the hymn. More inspiration in Jesus name
ReplyDeleteWhat's the tune, please!
ReplyDelete