Sunday, January 17, 2016

Isegun wa li okan mi

Isegun wa li okan mi
Nitori emi ngbe nu mi
Je ki igbi idanwo de
Jesu mura lati gba mi.

CHORUS

Isegun! Isegun!  'Segun L'okan mi
Moni isegun nla tori Jesu 
gb okan mi
Isegun! Isegun! bi odo sisan
Moni segun nla ninu eje Jesu.

Bi 'ja tile le t'o sipe
B'esu tile b' okan mi ja;
Sibe, mo je alagbara,
L'agbara Jesu, ngo segun.

Mo ni' segun lori ese

Mo ni'segun lori boji,
Ani iku ko nipa mo 
Halleluya! emi ti la.

No comments:

Post a Comment